From CAC Gospel Hymn Book
1. Fi ibukun Re tu wa ka,
Fi ayo kun okan wa;
K‘olukuluku mo ‘fe Re
K‘a l‘ayo n‘nu ore Re;
Tu wa lara tu wa l‘ara
La aginju aye ja.
2. Ope at‘ iyin l‘a nfun O
Fun ihinrere ayo;
Je ki eso igbala Re,
Po l‘okan at‘iwa wa;
Ki oju Re, ki oju Re
Ma ba wa gbe titi lo
3. Nje n‘igbat‘ a ba si pe wa
Lati f‘aye yi sile
K‘Angeli gbe wa lo s‘orun,
L‘ayo ni k‘a j‘ ipe na;
K‘a si joba, k‘a si joba
Pelu Kristi titi lae.
Amin.
https://play.google.com/store/apps/details?id=com.adediranife.cachymn
Comments
Post a Comment